Yoruba

YORUBA


Baba wa ti mbẹ li ọrun;
Ki a bọ̀wọ fun orukọ rẹ.
Ki ijọba rẹ de; Ifẹ tirẹ ni ki a ṣe, bi ti ọrun, bẹ̃ni li aiye.
Fun wa li onjẹ õjọ wa loni.
Dari gbese wa jì wa, bi awa ti ndarijì awọn onigbese wa.
Má si fà wa sinu idẹwò, ṣugbọn gbà wa lọwọ bilisi.


Baba ní ọrun, a gbadura fun gbogbo awọn alani aṣẹ agbaye kti o fi ọwọ kan wọn aiya ki awọn enia rẹ, àwọn èèyàn Ọlọrun, li alafia ati ifokanbale wa si rẹ Willki won ki o le yèBaba, darijì wọn; nitoriti nwọn kò mọ̀ ohun ti nwọn nṣe. 

Geen opmerkingen:

Een reactie posten